Anthony Daniels
From Wikipedia, the free encyclopedia
Anthony Daniels ( /ˈæntəni/ AN-tə-nee;[1] tí a bí ní ọjọ́ kanlélógún oṣù kejì ọdún 1946)[2] jẹ́ òṣèré ọmọ orílẹ̀ èdè Britain, tí ọ̀pọ̀lopọ̀ mọ̀ fún ipa gẹ́gẹ́ bi C-3PO nínú eré Star Wars mẹ́wàá.[lower-alpha 1]
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iṣẹ́ ...
Anthony Daniels | |
---|---|
Daniels ní ọdún 2011 | |
Ọjọ́ìbí | 21 Oṣù Kejì 1946 (1946-02-21) (ọmọ ọdún 78) Salisbury, Wiltshire, England |
Iṣẹ́ | Actor, mime artist |
Ìgbà iṣẹ́ | 1974–present |
Gbajúmọ̀ fún | C-3PO in Star Wars (1977–present) |
Olólùfẹ́ | Christine Savage (m. 1999) |
Website | anthonydaniels.com |
Close
Daniels ni ó fọ ohùn fún Legolas nínú eré Ralph Bakshi bẹ̀bí tí wọ́n ṣe fún The Lord of the Rings (1978). Ó ti farahàn nínú àwọn Britain kọ̀kan. Daniels jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n ní Entertainment Technology Center ti Yunifásitì Carnegie Mellon.[3]