Map Graph

Ìpínlẹ̀ Taraba

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

Taraba jẹ́ ìpínlẹ̀ ní àríwá-ìlà-oòrùn orílẹ̀ èdè Nàìjíríà, tí wọ́n sọọ́ ní orúkọ ní ìbámu pẹ̀lú odò Taraba ní èyí tí ó sàn jákèjádò gúúsù ìpínlẹ̀ náà. Olú-ìlú ìpínlẹ̀ Taraba ni Jalingo. Púpọ̀ àwọn olùgbe rẹ̀ ni Mumuye, Fulani, Jenjo, Wurkum, àti àwọn ẹ̀ya Kona ti wọ́n gbilẹ julọ apá àríwá ìpínlẹ̀ náà. Nígbàtí Jukun, Chamba, Tiv, Kuteb àti Ichen tí wọ́n ṣàwárí pé wọ́n gbilẹ̀ júlọ ní apá gúúsù ìpínlẹ̀ náà. Àárín gọ́gọ́tà ìpínlẹ̀ náà ni ó kún jùlọ fún àwọn ènìyàn Mambila, Chamba, Fulani àti Jibawa. Ó lé ní oríṣi ẹ̀yà mẹ́tàdìnlọ́gọ́rin, àti àwọn èdè wọn ní ìpínlẹ̀ Taraba.

Read article
Fáìlì:Mambila_Plateau_of_Taraba_State.jpgFáìlì:Taraba_State_Coat_of_Arms.pngFáìlì:Nigeria_-_Taraba.svgFáìlì:Donga_River,_Taraba_state.jpgFáìlì:Transportation_In_river_Lamido,_Taraba_State.jpgFáìlì:Gembu_Beautiful_Mountain.jpgFáìlì:The_Mambilla_Plateau,_Nigeria_09.jpgFáìlì:River_Donga.jpgFáìlì:Loop_traditional_dancer_from_Taraba_State_1.jpgFáìlì:Cijin_Lake_in_Gembu,_Taraba_state,_Nigeria.jpgFáìlì:Gashaka-Gumpti-National-Park-Taraba-State-780x520.jpgFáìlì:Nigeria_Taraba_State_map.png