Map Graph

Ìpínlẹ̀ Plateau

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà

{{Infobox settlement | name = Plateau | official_name = | type = [[ìpínlẹ̀ orílé-èdè Nàìjíríà|State]] | image_skyline = | image_alt = | image_caption = | image_flag = Plateau_State_Flag.jpg | flag_alt = Flag of Plateau State | image_seal = Plateau_State_Coat_of_arms.jpg | seal_alt = Seal of Plateau State | nickname = Home of Peace and Tourism | image_map = Nigeria - Plateau.svg | map_alt = | map_caption = Location of Plateau State in Nigeria | coordinates = 9°10′N 9°45′E | coor_pinpoint = | coordinates_footnotes = | subdivision_type = Country | subdivision_name =  Nigeria | established_title = Date created | established_date = 3 February 1976 | seat_type = Capital | seat = Jos | government_footnotes = | governing_body = Government of Plateau State | leader_party = APC | leader_title = Governor | leader_name = Simon Bako Lalong | leader_title1 = Deputy Governor | leader_name1 = Sonni Gwanle Tyoden | leader_title2 = Legislature | leader_name2 = Yakubu Yakson Sanda, Speaker Plateau State House of Assembly | leader_title3 = Senators | leader_name3 = C: Hezekiah Ayuba Dimka (APC)N: Istifanus Gyang (PDP)S: Nora Daduut (APC) | leader_title4 = Representatives | leader_name4 = Ahmed Idris Wase (APC) Beni Lar (PDP)Dachung Musa Bagos (PDP)Komsol Alphonsus Longgap (APC) Simon Davou Mwadkwon (PDP) Solomon Maren Bulus (PDP) Gagdi Adamu Yusuf (APC) Musa Agah (PDP) | unit_pref = Metric | area_footnotes = | area_total_km2 = 30913 | area_rank = 12 of 36 | area_note = | elevation_footnotes = | elevation_m = | population_footnotes = | population_total = 3,206,531 | population_as_of = 2006 | population_est = | pop_est_as_of = | population_rank = 26 of 36 | population_density_km2 = auto | population_note = | demographics_type1 = GDP (PPP) | demographics1_footnotes = | demographics1_title1 = Year | demographics1_info1 = 2007 | demographics1_title2 = Total | demographics1_info2 = $5.15 billion | demographics1_title3 = Per capita | demographics1_info3 = $1,587 | timezone1 = WAT | utc_offset1 = +01 | postal_code_type = postal code | postal_code = 930001 | area_code_type = | area_code = | blank_name_sec1 = HDI (2018) | blank_info_sec1 = 0.562medium · 22nd of 37 | iso_code = NG-PL | website = plateaustate.gov.ng | footnotes = }} Ìpínlẹ̀ Plateau jẹ́ Ìpínlẹ̀ ìkejìlá tí ó wà ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí ó tòní jùlọ. Ìpínlẹ̀ yí wà ní àárín gbùngbùn orílẹ̀-èdè Nàìjíríà tí àwọn òkè àpáta orísiríṣi sì yi ka, pàá pàá jùlọ ìlú Jos tí ó jẹ́ olú ìlú fún Ìpínlẹ̀ náà. Ìnagijẹ tí wọ́n ń pe Ìpínlẹ̀ yí ni Ilé Àlááfíà àti abẹ̀wò, ìdí ni wípé Ìpínlẹ̀ náà kún fún orísiríṣi ohun mère-mère tí ó ń wu ojú rí bíi iṣàn omi, àpáta láriṣiríṣi, òkè ńlá-ńlá ati bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ. Iye àwọn olùgbé ibẹ̀ jẹ́ mílíọ́nù mẹ́ta àti abọ̀.

Read article
Fáìlì:Terminus_market_traffic.jpg