Map Graph
No coordinates found

Kano

Kano jẹ́ olú ìlú Ìpínlè Kano àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìlú Ìbàdàn àti ìlú Èkó. Gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006, Kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — Kano Municipal, Fagge, Dala, Gwale, Tarauni àti Nasarawa — pẹ̀lú olùgbélú 2,163,225 ní ìkànìyàn ọdún 2006.

Read article
Fáìlì:KanofromDalaHill.jpg