From Wikipedia, the free encyclopedia
Tùnísíà (US /tuːˈniːʒə/ two-NEE-zhə or UK /tjuːˈnɪziə/ tew-NIZ-iə; Lárúbáwá: تونس Tūnis pronounced [ˈtuːnɪs]), lonibise bi Orile-ede Olómìnira ara Tùnísíà[note 1] (Lárúbáwá: الجمهورية التونسية al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah Àdàkọ:IPAc-ar), ni orile-ede apaariwajulo ni Áfríkà. O je orile-ede Maghreb kan, be si ni o ni bode mo Àlgéríà ni iwoorun, Libya ni guusuilaorun, ati Omiokun Mediterraneani si ariwa ati ilaorun. Aala re je 165,000 square kilometres (64,000 sq mi), pelu idiyele alabugbe to je egbegberun 10.4. Oruko re wa lati inu oruko oluilu re Tunis to budo si ariwa-ilaorun.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ará Tùnísíà Tunisian Republic الجمهورية التونسية al-Jumhūriyyah at-Tūnisiyyah | |
---|---|
Orin ìyìn: "Humat al-Hima" "Defenders of the Homeland" | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Tunis |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Arabic[2] |
Orúkọ aráàlú | Tunisian |
Ìjọba | Unitary Presidential Republic [2] |
• President | Kais Saied |
• Prime Minister | Ahmed Hachani |
• Prime Minister-designate | Mehdi Jomaa |
Independence | |
• from France | March 20, 1956 |
Ìtóbi | |
• Total | 163,610 km2 (63,170 sq mi) (92nd) |
• Omi (%) | 5.0 |
Alábùgbé | |
• 2014 estimate | 10,982,754[3] (79th) |
• 2011 census | 11,245,284[4] |
• Ìdìmọ́ra | 63/km2 (163.2/sq mi) (133rd (2005)) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $96.001 billion[5] |
• Per capita | $9,025.067[5] |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $43.684 billion[5] |
• Per capita | $4,106.747[5] |
Gini (2000) | 39.8 medium |
HDI (2010) | ▲ 0.683[6] Error: Invalid HDI value · 81st |
Owóníná | Tunisian dinar (TND) |
Ibi àkókò | UTC+1 (CET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+1 (not observed) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 216 |
ISO 3166 code | TN |
Internet TLD | .tn .تونس[7] |
Tunisia je orile-ede to kerejulo to budo si eba oke Atlas. Guusu orile-ede na je kiki aginju Sahara, pelu eyi to to je kiki ile olora ati eti okun 1,300 kilometres (810 mi). Awon mejeji ko ipa pataki igba atijo, akoko pelu ilu Carthage awon Punic, leyin re bi igberiko ile Romu ni Africa, to gbajumo bi "apere onje /bread basket" ile Romu. Leyin re, Tunisia bo so wo awon Vandals ni orundun 5k LK, awon Byzantine ni orundun 6k, ati awon Arabu ni orundun 8k. Labe Ileobaluaye Ottomani, Tunisia je mimo bi "Iluoba Tunis/Regency of Tunis". O bo sowo ibiabo Fransi ni 1881. Leyin ominira ni 1956 orile-ede na di "Ileoba Tunisia" leyin ijoba Lamine Bey ati Iran-oba Husainid. Pelu ifilole Orile-ede Olominira ara Tunisia ni July 25, 1957, olori aseolorile-ede Habib Bourguiba di aare akoko.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.