Ipinle Sokoto jé ikan ninu awon ipinle mérìndilógún tí o wà ní orile-ede Naijiria. Ìpínlè Sokoto wà ní àríwá ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà [1]Oruko gomina ipinle sokoto lowolowo bayii ni arakunrin Tanbuwal

More information Location, Statistics ...
Ipinle Sokoto
State nickname: Seat of the Caliphate
Location
Thumb
Statistics
Governor
(List)
Aminu Waziri Tambuwal (PDP)
Date Created 3 February 1976
Capital Sokoto
Area 25,973 km²
Ranked 16th
Population
1991 Census
2005 est.
Ranked 14th
4,392,391
4,244,399
ISO 3166-2 NG-SO
Close

Ijọba Ìbílẹ̀

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Sokoto jẹ́ mẹ́tàlẹ́lógún. Awon na ni:

  • Binji
  • Bodinga
  • Dange Shuni
  • Gada
  • Goronyo
  • Gudu
  • Gwadabawa
  • Illela
  • Isa
  • Kebbe
  • Kware
  • Rabah
  • Sabon Birni
  • Shagari
  • Silame
  • Sokoto North
  • Sokoto South
  • Tambuwal
  • Tangaza
  • Tureta
  • Wamako
  • Wurno
  • Yabo

Ilé ẹ̀kọ́ gíga

  • Usman Danfodio University of Sokoto[2]
  • Sokoto State University[3]
  • Umaru Ali Shinkafi Polytechnic Sokoto[4]
  • Shehu Shagari College of Education[5]

Itokasi

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.