Arméníà
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Arméníà (i /ɑrˈmiːniə/; Arméníà: Հայաստան, siso Hayastan, IPA: [hɑjɑsˈtɑn]), fún iṣẹ́ọba bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà (Հայաստանի Հանրապետություն, Hayastani Hanrapetut’yun, [hɑjɑstɑˈni hɑnɾɑpɛtuˈtʰjun]), je orile-ede oke-ile ti ile yika ni agbegbe Kafkasu ni Eurasia. O budo si oritameta Apaiwoorun Asia ati Apailaorun Europe,[14] o ni bode mo Turki ni iwoorun, Georgia ni ariwa, de facto Nagorno-Karabakh Republic alominira ati Azerbaijan ni ilaorun, ati Iran ati ile Azerbaijani Nakhchivan ni guusu.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Arméníà Republic of Armenia
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Yerevan 40°11′N 44°31′E |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Armenian[1] |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn (2011) | |
Ẹ̀sìn | Armenian Apostolic Church[4] |
Orúkọ aráàlú | Armenian |
Ìjọba | Unitary parliamentary republic |
• President | Vahagn Khachaturyan (Վահագն Խաչատուրյան) |
• Prime Minister | Nikol Pashinyan (Նիկոլ Փաշինյան) |
• President of the National Assembly | Alen Simonyan (Ալեն Սիմոնյան) |
Aṣòfin | National Assembly |
Establishment history | |
• Orontid dynasty | 6th century BC |
• Kingdom of Greater Armenia united under the Artaxiad Dynasty[5] | 190 BC[6] |
• Arsacid dynasty | 52–428 |
• Bagratid Armenia | 885–1045 |
• Kingdom of Cilicia | 1198–1375 |
• First Republic of Armenia declared | 28 May 1918 |
1936-1991 | |
21 September 1991 | |
Ìtóbi | |
• Total | 29,743 km2 (11,484 sq mi) (138th) |
• Omi (%) | 4.71[7] |
Alábùgbé | |
• 2020 estimate | 2,956,900 ▼ [8] (137th) |
• 2011 census | 3,018,854 ▼ [9][10] |
• Ìdìmọ́ra | 101.5/km2 (262.9/sq mi) (99th) |
GDP (PPP) | 2019 estimate |
• Total | $32.893 billion[11] |
• Per capita | $10,995[11] |
GDP (nominal) | 2019 estimate |
• Total | $13.444 billion[11] (127th) |
• Per capita | $4,527[11] (104th) |
Gini (2018) | Àdàkọ:IncreaseNegative 34.4[12] medium |
HDI (2018) | ▲ 0.760[13] high · 81st |
Owóníná | Dram (֏) (AMD) |
Ibi àkókò | UTC+4 (AMT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | +374 |
ISO 3166 code | AM |
Internet TLD |
|
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.