Ìpínlẹ̀ Kwara

Ìkan lára àwọn ìpínlẹ̀ ní orílé-èdè Nàìjíríà From Wikipedia, the free encyclopedia

Ìpínlẹ̀ Kwara

Kwara (Yorùbá: Ìpínlẹ̀ Kwárà) jẹ ìpínlẹ̀ ní apá ìwọ̀-oòrùn ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Olú-ìlú rẹ̀ ni ìlọrin. Ó wà ní àríwá àárín gbùngbùn ti a mò sí ìgbánú àárín ìlú. Yorùbá, pèlú ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn Nupe, Ìbàrìbá àti Fúlàní díẹ̀ ni wọ́n tẹ̀dó síbẹ.[1]

More information Location, Statistics ...
Ipinle Kwara
State nickname: State of Harmony
Location
Thumb
Statistics
Governor
(List)
Abdulrahman Abdulrasaq(APC)
Date Created 27 May 1967
Capital Ilorin
Area 36,825 km²
Ranked 9th
Population
1991 Census
2005 estimate
Ranked 31st
1,566,469
2,591,555
ISO 3166-2 NG-KW
Close

Ìpínlè kwárà ní ìjoba ìbílẹ̀ mérìndilógún, ìjoba ìpínlè ti ìwò oòrùn Ìlorin ni ènìyàn tó pòjù [2],Won da ipinle kwara sile ni ojo ketadinlogbon 1967 .

Ijọba Ìbílẹ̀

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Kwara jẹ́ mérìndilógún.[3] Awọn náà ní:

  • Asa
  • afon
  • Baruten
  • Bosubosu
  • Edu
  • Ekiti
  • Ifelodun
  • Ilorin East
  • Ilorin South
  • Ilorin West
  • Irepodun
  • Isin
  • Kaiama
  • Moro
  • Offa
  • Oke Ero
  • Oyun
  • Pategi

Awọn èdè

Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Kwara nítítò Ijọba ìbílẹ̀:

More information LGA, Awọn èdè ...
LGAAwọn èdè
AsaYoruba
BarutenBaatonum and Bokobaru
EduNupe
EkitiYoruba
IfelodunYoruba
Ilorin EastYoruba
Ilorin SouthYoruba
Ilorin WestYoruba
IsinYoruba
IrepodunYoruba
KaiamaBokobaru
MoroYoruba
OffaYoruba
Oke EroYoruba
Ọ̀yunYoruba
PategiNupe
Close

Àwọn èèyàn jànkànjànkàn

Àwọn ìtọ́kasí

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.