Kim Fields
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America From Wikipedia, the free encyclopedia
Kim Victoria Fields (ọjọ́ìbí May 12, 1969) ni òṣeré àti olúdarí ètò tẹlifísàn ará Amẹ́ríkà. Fields gbajúmọ̀ fún ìseré rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi Dorothy "Tootie" Ramsey nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn NBC The Facts of Life (1979–1988), àti gẹ́gẹ́ bíi Regine Hunter nínú eré aláwàdà ilé-iṣẹ́ tẹlifísàn Fox, Living Single (1993–1998). Fields ni ọmọ Chip Fields tí òhun náà jẹ̀ òṣeré àti olùdarí, àti ẹ̀gbọ́n Alexis Fields.
Kim Fields | |
---|---|
![]() Fields in 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Kim Victoria Fields 12 Oṣù Kàrún 1969 New York City, New York, U.S. |
Orúkọ míràn | Kim Fields Freeman |
Ẹ̀kọ́ | Pepperdine University |
Iṣẹ́ | Actress, director |
Ìgbà iṣẹ́ | 1977–present |
Gbajúmọ̀ fún | The Facts of Life, Living Single |
Olólùfẹ́ | Johnathon Franklin Freeman (m. 1995–2001) Christopher Morgan (m. 2007) |
Àwọn ọmọ | 2 |
Parent(s) | Chip Fields (mother) |
Àwọn olùbátan | Alexis Fields (sister) |
Àwọn Ìtọ́kasí
Wikiwand - on
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.