From Wikipedia, the free encyclopedia
Guinea-Bissau tabi Orile-ede Olominira ile Guinea-Bissau (pípè /ˈɡɪni bɪˈsaʊ/; Pọrtugí: República da Guiné-Bissau, pípè [ʁɛˈpublikɐ dɐ ɡiˈnɛ biˈsaw]) budo si Iwoorun Afrika. O ni bode mo Senegal ni ariwa, ati Guinea ni guusu ati ilaorun, ati mo Okun Atlantiki ni iwoorun.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Guinea-Bissau Republic of Guinea-Bissau República da Guiné-Bissau
| |
---|---|
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Bissau |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Portugi |
Lílò regional languages | Crioulo |
Orúkọ aráàlú | Bissau-Guinean(s)[1] |
Ìjọba | Orile-ede olominira sistemu aare die |
• Aare | Umaro Sissoco Embaló |
• Alakoso Agba | Rui Duarte de Barros |
Ilominira latodo Portugal | |
• Fifilole | 24 Osu Kesan, 1973 |
• Didamo | 10 Osu Kesan, 1974 |
• Ojo Ajodun Orile-ede | 24 Osu Kesan 24 |
Ìtóbi | |
• Total | 36,125 km2 (13,948 sq mi) (136th) |
• Omi (%) | 22.4 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 1,647,000[2] (148th) |
• 2002 census | 1,345,479 |
• Ìdìmọ́ra | 44.1/km2 (114.2/sq mi) (154th) |
GDP (PPP) | 2009 estimate |
• Total | $1.720 billion[3] |
• Per capita | $1,068[3] |
GDP (nominal) | 2009 estimate |
• Total | $826 million[3] |
• Per capita | $512[3] |
Gini (1993) | 47 high |
HDI (2007) | ▲ 0.396 Error: Invalid HDI value · 173rd |
Owóníná | West African CFA franc (XOF) |
Ibi àkókò | UTC+0 (GMT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | otun |
Àmì tẹlifóònù | 245 |
Internet TLD | .gw |
Aala ile re to 37,000 square kilometres (14,000 sq mi) pelu awon olugbe ti idiye won to 1,600,000.
Guinea-Bissau je ara ileoba Gabu nigbakan, to je apa Ileobaluaye Mali; awon apa ileoba wa titi di orundun kejidinlogun, nigba ti awon miran si je apa Ileobaluaye Portugal. Nigba na lo wa di ibiamusin Portugal toruko re unje Guinea Portugi ni orundun 19. Leyin ilominira, to je fifilole ni o̩dún 1973 to si je didamo ni o̩dún 1974, oruko oluilu re, Bissau, je fifikun mo oruko orile-ede lati dena iaru po mo Orile-ede Olominira ile Guinea.
14% nikan ni awon olugbe ti won mo ede onibise, Portugi so. Awon 44% nso Kriol, ede to da lori Portugi, awon yioku nso awon ede abinibi Afrika. Awon esin kanka ibe ni esin Islam ati awon esin ibile Afrika.
O je omo egbe Isokan Afrika, Agbajo Okowo awon Orile-ede Iwoorun Afrika, Agbajo Ipejo Onimale, Isokan Latini, Agbajo awon Orile-ede Ede Portugi, La Francophonie ati South Atlantic Peace and Cooperation Zone.
Gbogbo Ìpawó Orílẹ̀-èdè tenikookan re je ikan larin awon tokerejulo lagbaye.
Guinea-Bissau je pipin si awon agbegbe mé̩jo̩ ati apa ibi aladawa kan. Awon wonyi na tun wa je pinpin si apa metadinlogoji. Awon agbegbe ohun niyi:
|
Cities in Guinea-Bissau | |||||
---|---|---|---|---|---|
Rank | City | Population | Region | ||
1979 Census | 2005 estimate | ||||
1 | Bissau | 109,214 | 388,028 | Bissau | |
2 | Bafatá | 13,429 | 22,521 | Bafatá | |
3 | Gabú | 7,803 | 14,430 | Gabú | |
4 | Bissorã | N/A | 12,688 | Oio | |
5 | Bolama | 9,100 | 10,769 | Bolama | |
6 | Cacheu | 7,600 | 10,490 | Cacheu | |
7 | Bubaque | 8,400 | 9,941 | Bolama | |
8 | Catió | 5,170 | 9,898 | Tombali | |
9 | Mansôa | 5,390 | 7,821 | Oio | |
10 | Buba | N/A | 7,779 | Quinara | |
11 | Quebo | N/A | 7,072 | Quinara | |
12 | Canchungo | 4,965 | 6,853 | Cacheu | |
13 | Farim | 4,468 | 6,792 | Oio | |
14 | Quinhámel | N/A | 3,128 | Biombo | |
15 | Fulacunda | N/A | 1,327 | Quinara |
Religion in Guinea-Bissau,[4][5] | ||||
---|---|---|---|---|
religion | percent | |||
Islam | 50% | |||
Indigenous | 40% | |||
Christianity | 10% |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àdàkọ:Sisterlinks
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.