From Wikipedia, the free encyclopedia
Gíríìsì (English: /ˈɡriːs/ ( listen); Gíríkì: Ελλάδα, Elláda, IPA: [eˈlaða] ( listen); Èdè Grííkì Ayéijọ́un: Ἑλλάς, Hellás, IPA: [helːás]), bakanna gege bi Hellas ati fun ibise bi Helleniki Olominira (Ελληνική Δημοκρατία, Ellīnikī́ Dīmokratía, IPA: [eliniˈci ðimokraˈtia]),[9] je orile-ede kan ni guusuapailaorun Europe, o budo si apaguusu opin Balkan Peninsula. Griisi ni ile bode mo Albania, Olominira ile Makedonia ati Bulgaria si ariwa, ati Turki si ilaorun. Okun Aegeani dubule si ilaorun re, the Okun Ioniani si iwoorun, ati Okun Mediterraneani si guusu. Griisi ni o ni etiodo kewa togunjulo ni agbaye toje 14,880 km (9,246.00 mi) ni gigun, ti o ni opolopo iye awon erekusu (bi 1400, 227 ni ibi ti aon eniyan ngbe), ninu won ni Crete, Dodecanese, Cyclades, ati awon Erekusu Ioniani. Bi ogorin ninu ogorun ile Griisi ni o je ti awon oke, ninu ibi ti Oke Olympus ni o gajulo to je 2,917 m (9,570.21 ft).
Orílẹ̀-èdè Olómìnira Hẹ́llẹ́nẹ̀ Hellenic Republic Ελληνική Δημοκρατία Ellīnikī́ Dīmokratía | |
---|---|
Motto: Eleftheria i Thanatos, (Greek: "Ελευθερία ή Θάνατος", "Freedom or Death") (traditional) | |
Ibùdó ilẹ̀ Gíríìsì (green) – on the European continent (light green & grey) | |
Olùìlú àti ìlú tótóbijùlọ | Athens |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Greek |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | 94% Greek, 4% Albanian, 2% others[1][2][3][4] |
Orúkọ aráàlú | Greek |
Ìjọba | Parliamentary republic |
• Ààrẹ | Katerina Sakellaropoulou (Κατερίνα Σακελλαροπούλου) |
• Alákóso Àgbà | Kyriakos Mitsotakis (Κυριάκος Μητσοτάκης) |
Aṣòfin | Parliament |
Modern statehood | |
25 March 1821 | |
• Recognized | 3 February 1830, in the London Protocol |
7 May 1832, in the Convention of London | |
• Current constitution | 11 June 1975, Third Hellenic Republic |
Ìtóbi | |
• Total | 131,990 km2 (50,960 sq mi) (96th) |
• Omi (%) | 0.8669 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 11,305,118[5] (74th) |
• 2011 (preliminary data) census | 10,787,690[6] |
• Ìdìmọ́ra | 85.3/km2 (220.9/sq mi) (88th) |
GDP (PPP) | 2010 estimate |
• Total | $318.082 billion[7] (37th) |
• Per capita | $28,434[7] (29th) |
GDP (nominal) | 2010 estimate |
• Total | $305.415 billion[7] (32nd) |
• Per capita | $27,302[7] (29th) |
Gini (2005) | 33[8] Error: Invalid Gini value |
HDI (2011) | ▲ 0.861 Error: Invalid HDI value · 29th |
Owóníná | Euro (€)2 (EUR) |
Ibi àkókò | UTC+2 (EET) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+3 (EEST) |
Irú ọjọ́ọdún | dd/mm/yyyy |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | right |
Àmì tẹlifóònù | 30 |
Internet TLD | .gr3 |
|
Griisi oni fa gbongbo de asa-olaju Griisi ayeijoun, nibi ti gbogbo eniyan gba bi ibusun asa-olaju Apaiwoorun. Nitori eyi o je ibi ibere oseluaralu,[10] imoye Apaiwoorun,[11] Awon Idije Olympiki, litireso Apaiwoorun ati itankiko, sayensi oloselu, awon ipile sayensi ati mathematiki pataki, ati drama,[12] ati trajedi ati awada. Asesile yi han gedegbe ninu awon Ibi Oso Agbaye UNESCO 17 ti won wa ni Griisi.
Griisi je orile-ede adagbasoke to ni Human Development Index giga,[13][14][15][16] Griisi ti je omo egbe Isokan Europe lati 1981 ati Isokan Okowo ati Owonina Europe lati 2001,[17] NATO lati 1952,[18] ati Ile-ise Ofurufu Europe lati 2005.[19] Bakanna o tun je omo egbe latibere Isodokan awon Orile-ede, OECD,[20] ati Agbajo Ifowosowopo Okowo ni Okun Dudu. Atensi ni oluilu re; awon ilu pataki miran nibe tun ni Thessaloniki, Patras, Heraklion ati Larissa.
Fun amojuto, Griisi ni periferi metala ti won je pipin si ibile mokaleladota ([nomoi] error: {{lang}}: text has italic markup (help), singular Gíríkì: nomos). Bakanna ni agbegbe idawa kan wa to n je Oke Athos (Gíríkì: Agio Oros, "Oke Mimo"), to ni bode mo periferi Central Macedonia.
Map | Number | Periphery | Capital | Area (km²) | Area (sq mi) | Population |
---|---|---|---|---|---|---|
1 | Attica | Athens | 3,808 | 1,470 | 3,761,810 | |
2 | Central Greece | Lamia | 15,549 | 6,004 | 605,329 | |
3 | Central Macedonia | Thessaloniki | 18,811 | 7,263 | 1,871,952 | |
4 | Crete | Heraklion | 8,259 | 3,189 | 601,131 | |
5 | East Macedonia and Thrace | Komotini | 14,157 | 5,466 | 611,067 | |
6 | Epirus | Ioannina | 9,203 | 3,553 | 353,820 | |
7 | Ionian Islands | Corfu | 2,307 | 891 | 212,984 | |
8 | North Aegean | Mytilene | 3,836 | 1,481 | 206,121 | |
9 | Peloponnese | Kalamata | 15,490 | 5,981 | 638,942 | |
10 | South Aegean | Ermoupoli | 5,286 | 2,041 | 302,686 | |
11 | Thessaly | Larissa | 14,037 | 5,420 | 753,888 | |
12 | West Greece | Patras | 11,350 | 4,382 | 740,506 | |
13 | West Macedonia | Kozani | 9,451 | 3,649 | 301,522 | |
- | Mount Athos (Autonomous) | Karyes | 390 | 151 | 2,262 |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.