From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwọn àdán ní àwọn ẹranko afọmúbọ́mọ tí wọ́n wà nínú ìtòsílẹ̀ àwọn ẹranko Ọlọ́wọ́-ìyẹ́ tàbí Chiroptera;[lower-alpha 1] tí wọ́n ún lo apá wọn bíi ìyẹ́-ìfò, àwọn níkan ní ẹranko afọmúbọ́mọ tí wọ́n le fò.
Àdán | |
---|---|
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ e ] | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Clade: | Scrotifera |
Ìtò: | Chiroptera (Ọlọ́wọ́-ìyẹ́) Blumenbach, 1779 |
Suborders | |
(traditional):
(recent):
| |
Worldwide distribution of bat species |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.