Remove ads
From Wikipedia, the free encyclopedia
Kasino je ibi ti iru awon tete kan ti un sele. O wopo ki a ri awon kasino ni ile itura, ile onje, ile itaja, ninu oko oju-omi igbadun ati ni awon ibi ibewo miran. Awon kasino miran un gbalejo awon faaji live bi awada oniyeye, orin ori-itage, ati awon ere idaraya.
"Kasino" gege bi oro wa lati ede Italia, gbongbo oro na ni "Casa" (ile) to tumo teletele si ile kekere. Oro yi yipada lati tumosi ile igbadun nibi ti ijo, orin ati tete ti n waye.
Apere awon iru kasino bayi wa ni Villa Giulia ati Villa Farnese. Ni ede italia odeoni, oro yi un tokasi ile asewo (bakanna bi "casa chiusa", to tumosi "ile titi"), nigbati ile tete un je kiko bi casinò pelu ami oro.[1]
Ni orundun 19, itumo "kasino" tun je awon ile igboro nibi ti orisirisi igbadun bi tete, ere idaraya ti n sele. Apere iru ile bayi ni Newport Casino ni Newport, Rhode Island.
Ki se gbogbo kasino lo wa fun ayo tita. Copenhagen Casino je ile tiata, ibiyi ni opolopo awon eniyan pejo si fun ipade nigba Ijidide 1848 ni Denmark to so ibe di orile-ede oba olofin ibagbepo. Titi odun 1937 o si je tiata to gbajumo.[2] Hanko Casino to budo si Hanko, Finland ki se fun tete. Ile alejo lo je fun awon alade lati Rosia ti won be ibe wo fun igbadun spa ni opin awon odun 1800, loni won n lo gege bi ile onje. Ibi to n je "Kasino",[3] ni Avalon Harbor ni Erekusu Katalina, ko je fun ayo tita nitoripe ofin de tete nigbati won ko ni Kalifonia.
A ko mo bi tete se bere. Awon omo Saina ni won koko se akosile re ni odun 2300 kJ, sugbon o je gbigba wipe imuse tete, lona kan tabi omiran, ti waye ni gbogbo awujo eniyan ninu itan. Lati ori awon Griiki ayeijoun ati awon ara Romu de ile Fransi nigba Napoleon ati Ilegeesi nigba Elisabeti, itan kun fun iroyin nipa tete tita.[4]
Ikan ninu kasino akoko ti a mo ni Casinò di Venezia, ni Venice Italy larin 1638.[5] O hun sise doni.Ọpọlọpọ awọn orilẹ-ede ti wa ni idinamọ lati awọn iṣẹ ṣiṣe ṣiṣiṣẹ, nitorinaa wọn ti yọ ni kasino ti o wa ninu ọkọ oju-omi igbadun. Iru awọn Casino n ṣiṣẹ nigbati wọn ba wa ni okun ni awọn ita, nitorinaa wọn ko ofin nipasẹ ofin.[6]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.