Agbegbe Ijoba Ibile Biriniwa je ijoba ibile ni Ipinle Jigawa ni Nigeria. Gbogbo agbegbe naa je kilomita 1.567, nigbati awon olugbe be je 142,329.

Ọjà èso water melon tí ó wà ní Birniwa


Itokasi

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.