From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré jẹ́ àwo róbótó tí ó wà lára ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po, tí ó wà ní bíi àárín ìyípo Mars àti Jupiter. Àwọn àkórajọ onírúurú tí kò dúró déédé tí wọ́n ń pè ní ástẹ́rọ́ìdì tàbí àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ló gba inú rẹ̀. Wọ́n tún máa ń pe ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré ní ojúlówó ìgbàjá àwọn ìsọ̀gbé oòrùn kékeré tàbí ojúlówó ìgbàjá lati jẹ́ kí ìyàtọ̀ wá láàárín rẹ̀ àti àwọn míràn tí wọ́n wà lágbo ètò ìdarísí oòrùn tí ó ṣàkójọpọ̀ oòrùn àti àwọn ohun tí ó ń yíi po bíi Awon asteroidi itosi Aye ati awon asteroidi troja.[1]
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.