From Wikipedia, the free encyclopedia
Èdè Azerbaijani
Azerbaijani | |
---|---|
Azərbaycan dili (Latin script) Азәрбајҹан дили (Cyrillic script) آذربایجان دیلی (Perso-Arabic script) | |
Ìpè | /azærbajdʒan dili/ |
Sísọ ní | Iran, Azerbaijan Georgia, Jẹ́mánì Russia, Estonia UK USA Uzbekistan Syria Iraq[1], Turkey, Turkmenistan Ukraine, Canada |
Ìye àwọn afisọ̀rọ̀ | 20-31 million [2][3][4][5][6] [7] |
Èdè ìbátan | |
Sístẹ́mù ìkọ | Latin alphabet for North Azeri in Azerbaijan, Perso-Arabic script for South Azeri in Iran, and, formerly, Cyrillic alphabet for North Azeri (Azerbaijani variants) |
Lílò bíi oníbiṣẹ́ | |
Àkóso lọ́wọ́ | Kòsí àkóso oníbiṣẹ́ |
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè | |
ISO 639-1 | az |
ISO 639-2 | aze |
ISO 639-3 | variously: aze – Azerbaijani (generic) azj – North Azerbaijani azb – South Azerbaijani |
Ọmọ ẹgbẹ́ ni èdè yìí jẹ́ fún ẹgbẹ́ èdè tí a ń pè ní Turkic. Ẹgbẹ́ èdè Turkic yìí jẹ́ ọmọ ẹbí Altaic. Àwọn tí ó ń sọ Azerbaijani tó mílíọ̀nù mẹ́rìnlá ní Azerbaijan ní ibi tí wọ́n ti ń lò ó gẹ́gẹ́ bí èdè ìṣe ìjọbi. Wọ́n tún ń sọ èdè yìí ní Turkey, Syria àti Afgloanistan. Wọ́n tún máa ń pe èdè yìí ni Azeri. Àkọtọ́ Cyrillic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Azerbaijan ṣùgbọ́n àkọtọ́ Arabic ni wọ́n fi ń kọ ọ́ sílẹ̀ ní Iran. Wọ́n fi ojú èdá èdè pín wọn sí Swuthern Azerbaijani) àti Northern Azerbaijani tí mílíọ̀nù méje ènìyàn ń sọ.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.