Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè

Egbé àwọn Ìjoba Orílẹ̀-èdè From Wikipedia, the free encyclopedia

Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè
Remove ads

Àjọ Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè tabi Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè ni soki (ní èdè Geesi: UNO tàbí UN) jẹ́ àgbájọ káríayé ti eto re je lati fa ifowosowopo ninu ofin kakiriaye, abo kakiriaye, idagbasoke eto inawole, ilosiwaju awujo, eto omoniyan ati imudaju alafia lagaye. OA je didasile ni odun 1945 leyin Ogun Agbaye Keji lati sedipo Apejo awon Orile-ede, lati jawo awon ogun larin awon orile-ede, ki o si pese aye fun ijiroro larin won. O ni opolopo eka akojoegbe kekeke lati le se awon ise wonyi.

Thumb
Quick Facts Arabic:, Chinese: ...
Remove ads
Thumb
Àjọ àwọn Orílẹ̀-èdè , Geneva
Remove ads

Itokasi

Loading content...
Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads