![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/b8/WoleSoyinka2015.jpg/640px-WoleSoyinka2015.jpg&w=640&q=50)
Wọlé Sóyinká
Akéwì ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Akínwándé Olúwọlé Babátúndé Ṣóyínká (ọjọ́ìbí 13 July 1934) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n (Professor) nínú Ìmọ̀ Lítíréṣọ̀ (literature), alákọsílẹ̀, eré orí ìtàgé (playwright) àti akéwì (poet). Wọlé Sóyinká jẹ́ ògidì ọmọ Yorùbá lórílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó gba Ẹ̀bùn Nobel ní ọdún 1986 fún iṣẹ́ ọwọ́ ọ rẹ̀ lórí i ìgbéga ìmọ̀ ìkọ̀wé.[2].
Quick Facts Ọjọ́ ìbí, Iṣẹ́ ...
Wọlé Sóyinká | |
---|---|
![]() Wọlé Sóyínká ní 2018 | |
Ọjọ́ ìbí | Akínwándé Olúwolé Babátúndé Sóyíinká[1] 13 Oṣù Keje 1934 (1934-07-13) (ọmọ ọdún 89) Abeokuta, Nigeria Protectorate (now Ogun State, Nigeria) |
Iṣẹ́ |
|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
Ẹ̀kọ́ | Abeokuta Grammar School University of Leeds |
Ìgbà | 1957–present |
Genre |
|
Subject | Comparative literature |
Notable awards | Nobel Prize in Literature 1986 Academy of Achievement Golden Plate Award 2009 |
Close