From Wikipedia, the free encyclopedia
Ibi Ọ̀ṣọ́ Àgbáyé UNESCO je ibi (bi egan, okeile, adagun, asale, iboji, ileigbe, complex, tabi ilu) to wa ninu akojo ti Eto Oso Agbaye akariaye se ti Igbimo Oso Agbaye UNESCO unsedari, to ni awon orile-ede 21 gege bi omo egbe[1] ti won je didiboyan latowo Ile-igbimo Gbogbogboo fun igba odun- merin kan.[2] Ibi Oso Aye je ibi to se pataki fun asa tabi nitori boseri.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.