Àwọn Tuareg

From Wikipedia, the free encyclopedia

Àwọn Tuareg
Remove ads

Àwọn Tuareg (bakanna bi Twareg tabi Touareg, Beriberi: Imuhagh) je awon eniyan Beriberi adaeran alarinka. Awon ni won poju ti won ungbe ni Sahara ni arin Ariwa Afrika.[2][3] Won pe ara won ni Kel Tamasheq tabi Kel Tamajaq ("Awon to unso Tamasheq"), Imuhagh, Imazaghan tabi Imashaghen ("eniyan Olominira"), tabi Kel Tagelmust, i.e., "Awon afaso boju".[4]

Quick Facts Àpapọ̀ iye oníbùgbé, Regions with significant populations ...
Remove ads

Itokasi

Loading related searches...

Wikiwand - on

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Remove ads