Toyin Abraham[3] tàbí Olutoyin Aimakhu; ni wọ́n bí ní (September 5, 1984). Ó jẹ́ òṣèré orí ìtàgé , olùgbéré-jáde àti adarí eré, ọmọ rílẹ̀-èdè Nàìjíríà.[4][5][6][7]
Quick Facts Toyin Abraham, Ọjọ́ìbí ...
Toyin Abraham |
---|
Toyin Abraham at AMVCA 2020 |
Ọjọ́ìbí | 5 Oṣù Kẹ̀sán 1980 (1980-09-05) (ọmọ ọdún 43) Auchi, Edo, Nigeria |
---|
Orílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nigerian |
---|
Iṣẹ́ |
- actress
- filmmaker
- producer
- director
|
---|
Ìgbà iṣẹ́ | 2003–present |
---|
Olólùfẹ́ | Kolawole Ajeyemi[1][2] |
---|
Close