Pakístàn
orílẹ̀-èdè ní Ásíà / From Wikipedia, the free encyclopedia
Pakístàn (/ˈpækɪˌstæn/ ( listen) tabi /ˌpɑkɨˈstɑːn/ ( listen); Urdu: پاکِستان) (Pípè ní Urdu: [paːkɪsˈtaːn] ( ẹ tẹ́tí gbọ́)), lonibise bi Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn (Urdu: اسلامی جمہوریہ پاکِستان) je orile-ede kan ni Guusu Asia. O ni ile etiomi to to 1,046-kilometre (650 mi) leba Omiokun Arabia ati Omiala Oman ni guusu, be sini o ni bode mo Afghanistan ati Iran ni iwoorun, India ni ilaorun ati Shaina ni ookan ni ariwailaorun.[7] Bakanna Tajikistan na sunmo Pakistan sugbon aaye Odede Wakhan tinrin pin won soto. Letanletan o budo si ipo larin awon agbegbe pataki Guusu Asia, Alaarin Asia ati Ibiarin Ilaorun.[8]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Órílẹ̀-èdè Olómìnira Onímàle ilẹ̀ Pakístàn Islamic Republic of Pakistan اسلامی جمہوریہ پاکستان Islāmī Jumhūrī-ye Pākistān | |
---|---|
Motto: Unity, Discipline, Faith (Urdu: اتحاد، تنظيم، يقين مُحکم) Ittehad, Tanzeem, Yaqeen-e-Muhkam | |
Orin ìyìn: Qaumī Tarāna | |
Olùìlú | Islamabad |
Ìlú tótóbijùlọ | Karachi |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Urdu (National) English |
Lílò regional languages | Balochi, Pashto, Punjabi, Saraiki, Sindhi [1] |
Orúkọ aráàlú | Pakistani |
Ìjọba | Federal Parliamentary republic |
• Founder | Muhammad Ali Jinnah |
• President | Asif Ali Zardari (PPP) |
• Prime Minister | Shehbaz Sharif (PML-N) |
• Chief Justice | Qazi Faez Isa |
• Chair of Senate | Sadiq Sanjrani (BAP) |
• House Speaker | Raja Pervaiz Ashraf (PPP) |
Aṣòfin | Majlis-e-Shoora |
• Ilé Aṣòfin Àgbà | Senate |
• Ilé Aṣòfin Kéreré | National Assembly |
Formation | |
• Pakistan Declaration | January 1933 |
• Pakistan Resolution | 23 March 1940 |
• Independence | from the United Kingdom |
• Declared | 14 August 1947 |
• Islamic Republic | 23 March 1956 |
Ìtóbi | |
• Total | 796,095 km2 (307,374 sq mi) (36th) |
• Omi (%) | 3.1 |
Alábùgbé | |
• 2024 estimate | 170.6 million[2] (6th) |
• 1998 census | 132,352,279[3] |
• Ìdìmọ́ra | 214.3/km2 (555.0/sq mi) (55th) |
GDP (PPP) | 2010 estimate |
• Total | $451.972 billion[4] |
• Per capita | $2,713[4] |
GDP (nominal) | 2010 estimate |
• Total | $177.901 billion[4] |
• Per capita | $1,067[4] |
Gini (2005) | 31.2 medium |
HDI (2007) | ▲ 0.572[5] Error: Invalid HDI value · 141st |
Owóníná | Pakistani Rupee (Rs.) (PKR) |
Ibi àkókò | UTC+5 (PST) |
• Ìgbà oru (DST) | UTC+6 (PDT) |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | left[6] |
Àmì tẹlifóònù | 92 |
ISO 3166 code | PK |
Internet TLD | .pk |