From Wikipedia, the free encyclopedia
Otto Eduard Leopold von Bismarck (1 April 1815 – 30 July 1898) je asiwaju ara Prussia/Jemani ti opin orundun 19th, ati eni pataki ni aye igbana. Gege bi Ministerpräsident, tabi Alakoso Agba ile Prussia lati 1862–1890, o samojuto iparapo ile Jemani. O seilale Ile Obaluaye Jemani ni 1871, o si di Kansilo akoko ibe, o si solori ibe titi di igba ti won le kuro ni 1890. Ona isediplomati re Realpolitik ati ona to fi agbara joba je ki wo o fun ni oruko ""Kansilo Lile" ("The Iron Chancellor").
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Otto von Bismarck | |
---|---|
Otto von Bismarck in August 1890 | |
1st Kánsílọ̀ ilẹ̀ Jẹ́mánì | |
In office 21 March 1871 – 20 March 1890 | |
Monarch | Wilhelm I (1871–1888) Frederick III (1888) Wilhelm II (1888–1890) |
Asíwájú | First Chancellor |
Arọ́pò | Leo von Caprivi |
9th Minister President of the Kingdom of Prussia | |
In office 23 September 1862 – 1 January 1873 | |
Monarch | Wilhelm I |
Asíwájú | Adolf of Hohenlohe-Ingelfingen |
Arọ́pò | Albrecht von Roon |
11th Minister President of the Kingdom of Prussia | |
In office 9 November 1873 – 20 March 1890 | |
Monarch | Wilhelm I (1873–1888) Frederick III (1888) Wilhelm II (1888–1890) |
Asíwájú | Albrecht von Roon |
Arọ́pò | Leo von Caprivi |
Federal Chancellor of the North German Confederation | |
In office 1867–1871 | |
Ààrẹ | Wilhelm I |
Asíwájú | Confederation established |
Arọ́pò | German Empire |
23rd Foreign Minister of the Kingdom of Prussia | |
In office 1862–1890 | |
Monarch | Wilhelm I (1862–1888) Frederick III (1888) Wilhelm II (1888–1890) |
Asíwájú | Albrecht von Bernstorff |
Arọ́pò | Leo von Caprivi |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Schönhausen, Prussia | 1 Oṣù Kẹrin 1815
Aláìsí | 30 July 1898 ọdún 83) Friedrichsruh, German Empire | (ọmọ
Ẹgbẹ́ olóṣèlú | None |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Johanna von Puttkamer |
Signature |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.