Oníṣe:Agbalagba/Ramadan
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ramadan (/ˌræməˈdɑːn/ /ˌræməˈdɑːn/; Lárúbáwá: رمضان Ramaḍān, IPA: [ramaˈdˤaːn];[note 1] ni won tun n donape ni Ramazan, romanized gege bi Ramzan, Ramadhan, tabi Ramathan) ni osu Kesan ninth month ninu awon osu oju-orun Islamic calendar,[1] gbogbo Musulumi agbaye ni won mo osu naa gege bi osu awe. (fasting) (Sawm) lati gbola fun isipaya Al-Qurani si Muhammad (first revelation of the Quran to Muhammad) gege bi igbagbo esin Islam.[2][3] Won ma n fi osu yi gbawe ni eekan lodun gege bi opo kan ninu awon opo esin Islam (Five Pillars of Islam).[4] Osu yi ma n je mokandin-logbon tabi ogbon ojo geerege (29–30 days) o da lori riri iletesu naa (crescent moon), gege bi opolop akosile orisirisi ninu hadiths.[5][6]
رمضان Ramadan | |
---|---|
![]() | |
Observed by | Muslims |
Type | Religious |
Begins | 1 Ramadan |
Ends | 29 or 30 Ramadan |
Date | Variable (follows the Islamic lunar calendar) |
Celebrations | Community iftars and Community prayers |
Observances |
|
Related to | Eid al-Fitr, Laylat al-Qadr |
Gbolohun Ramadan wa lati inu ede Larubawa ramiḍa tabi ar-ramaḍ, ni eyi to tumo si ooru gbigbona tabi ogbele.[7] Awe gbigba je dandan obligatory fun Musulumi to ba ti balaga, awe kii se dan dan fun awon ti won n saare, arinrin-ajo,arugbo, alaboyun, obinrin to n fomo lomu, alatosi egbe tabi eni ti saare iku ati obinrin to n se nkan osu.[8] Awe gbigba di dan dan (wājib) fun awon Musulumi ninu osu Sha'ban, leyin odun keji ti awon Musulumi se iri ajo lati ile Meka Mecca lo si Medina. Awon Musulumi ti won wa ni agbegbe ajakale arun wa bi: ki osan doru o tele eto Meka nipa lilo 'Fatwas' [9] Sugbon, aba ti won gba wole ni ki awon Musulumi ti o wa nirufe agbegbe bee o tele ilana eto ilu ti sunmo won julo ni eyi ti osan ati oru ko dapo mora won.
Won ma n gbawe lati idaji titi di ti Orun ba wo, won ko ki ma n je ounje, won ki mu ohun kohun tabi ba obinrin lo po. Won tun ma n jina si ohun ese ti o le kodi ere awe won gege bi: iro pipa, eke sise, oro eyin siso, epe,ija yato si ti o ba fe fi gba emi ara re kale lowo ewu (self defense).[10][11] Ounje idaji saaju ki won to bere awe ni won pe ni (Saari) Suhoor, nigba ti ounje leyin awe ni won n pe ni Iftar.[12][13] Ere emi (thawab) fun awe gbigba ni won tun gbagbo wipe o ma n po ni inu osu Ramadan.[14] Awe gbigba run awon Musulumi ninu osu Ramadan ni o sokunfa opo adura salat (prayers), kika Quran[15][16] ati alekun dara dara ati ore tita.