Old Town of Prague
From Wikipedia, the free encyclopedia
Old Town of Prague (Tsẹ́kì: [Staré Město pražské] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) nibó jẹ́ ìletò kan tí ó ti wà tipẹ́ ní ìlú Prague, ní orílẹ̀-èdè Czech Republic. Wọ́n yà á sọ́tọ̀ láti ìta pẹ̀lú odi kérébété kan tí wọ́n pè ní Vltava tí ó sì ní odò ní apá ọ̀tún ati apá òsì. Kòtò yí ni wọ́n fi òpópó oríṣiríṣi bò mọ́lẹ̀ láti apá (north sí south-west) Revoluční, Na Příkopě, àti ìyẹn Národní tí ó sì jẹ́ ààlà fún abúlé cadastral ní Old Town. Àmọ́ ó ti di ìkan lára Prague 1 nísìnyí.
Lára àwọn ibi tí wọ́n gbajúmọ̀ ní Old Town ni: Old Town Square àti Astronomical Clock. Old Town ni àwọn ìlú bíi New Town of Prague yí po. Nísọdá afárá odò Vltava tí ó so afárá Charles Bridge ni Lesser Town of Prague (Tsẹ́kì: [Malá Strana] error: {{lang}}: text has italic markup (help)). Ìlú àwọn Júù tẹ́lẹ̀ (Josefov) nió wà ní apá àríwá Old Town tí ó dojú kọ ìlú Vltava.