Leo Tolstoy
From Wikipedia, the free encyclopedia
Leo Tolstoy, tabi Count Lev Nikolayevich Tolstoy (Rọ́síà: Лев Никола́евич Толсто́й (ìrànwọ́·ìkéde), Pípè ní èdè Rọ́síà: [lʲɛv nʲɪkɐˈlaɪvʲɪtɕ tɐlˈstoj]; September 9 [O.S. August 28] 1828 – November 20 [O.S. November 7] 1910), je olukowe ara orile-ede Russia to je gbigba gege bi ikan ninu awon olukotan aroko to je olokikijulo. Awon iwe re Ogun ati Alafia ati Anna Karenina.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |