Julie Benz
Òṣèré Ọmọ Orílẹ̀-èdè America / From Wikipedia, the free encyclopedia
Julie Marie Benz ( Ojo Ibi ojo kini osu karun ,1972) osere birin ile Amerika, ti a mo si Darla ninu Buffy the Vampire Slayer ati Angel (1997–2004) ati Rita Bennett ninu Dexter (2006–2010), ninu eyi ti o ti gba ami eye satelaiti fun Osere birin ti oni ifowosopo ni odun 2006 ati ami eye Satun ni 2009. O ko pa ninu Roswell series (1999–2000), Desperate Housewives (2010), ( Ko si ebi lasan)No Ordinary Family (2010–2011), (Okunrin to le bun) The Gifted Man (2011–2012),Defiance (2013–2015), and Hawaii Five-0 (2015-present). Awon Ipa re niyi Jawbreaker (1999), The Brothers (2001), Rambo , Saw V and Punisher: War Zone (2008), The Boondock Saints II: All Saints Day (2009), and Bedrooms (2010).