From Wikipedia, the free encyclopedia
Jaja ilu Opobo
Jàjá ìlú Òpobò Jaja of Opobo | |
---|---|
Amanyanabo | |
[[File:|frameless|alt=]] Jàjá ìlú Òpobò, Opobo | |
Orí-ìtẹ́ | 25 December 1870–September 1887 |
Orí-oyè | 25 December 1870 |
Orúkọ | Jubo Jubogha "Jaja" |
Language | Igbo |
Ọjọ́ìbí | c. 1821 |
Ibíbíbísí | Orlu[citation needed] |
Aláìsí | c. 1891 |
Ìsìnkú | Opobo |
Aṣájú | None |
Arọ́pọ̀ | Perekule |
Ẹbíajọba | Jaja |
Bàbá | Ozurumba |
Ìyá | Uru |
Ọba Jaja tí ìlú Opobo (Orúkọ: Jubo Jubogha, 1821 - 1891) jẹ́ ọmọba oníṣòwò, òun sì ní olùdásílẹ̀ ìlú Opobo, tí ó wà ní ìlú Ìpínlẹ̀ Rivers tí ìlú Nàìjíríà. Wọ́n bí ni Umuduruoha Amaigbo ní ìpínlẹ̀ Imo, ọ̀dọ̀ ló wà nígbà tí àwọn afẹ́rú-ṣòwò mú lẹ́rú ní Bonny. Orúkọ tó padà jẹ́ ni "Jájá"
Jaja of Opobo: Ní ọdún 1792, Jaja of Opobo di Ọba Banny. Ó kú ní 1829.
Mohammed Bello: Mohammed Bello tí ó jẹ́ ọmọ Uthman dan fodio kọ́ ìlú Sokoto ní 1809. Ní 1817 nígbà tí baba rẹ̀ kú, ó di Caliph ibẹ̀.
Shódẹkẹ́: Ní 1825, Shódẹkẹ́ di aṣáájú àwọn Ẹ̀gbá ní Abẹ́òkúta.
Baálẹ̀ Ìbàdàn: Ní ọdún 1830, wọ́n dá Ìbàdàn sílẹ̀ ó sì ní Baálẹ̀ àkọ́kọ́
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.