From Wikipedia, the free encyclopedia
Irì, erì, enini tabí nini jẹ́ omi kan tí ó ma ń sẹ tàbí kóra jọ sí orí ewé, koríko tàbí ohun kan mìíràn tí ó bá wà ní abẹ́ sánmọ̀ ní òru mọ́jú tàbí lásìkò tí ojú ọjọ́ bá bora.[1]
Ohun tí ìmọ̀ fún múlẹ̀ ni wípé nígbà tí oru tàbí ìgbóná ojú ọjọ́ bá ń bora tí afẹ́fẹ́ tutù ń fẹ́, oru ara àwọn ewéko àti àwọn ohun mìíràn tó ti gbóná jan jan lójú ọjọ́ tẹ̀lẹ̀ yóò ma ṣe oru èyí tí kò láyè láti gbéra gòkè lọ tí wọ́n ń pè ní (evaporation), ìjákulẹ̀ yí ni ó ma ń fàá tí irúfẹ́ oru bẹ́ẹ̀ fi ma ń silẹ̀ sí orí àwọn ewéko gbogbo.<ref>"dew". The Columbia Encyclopedia, 6th ed. The Columbia Encyclopedia, 6th ed. Retrieved 18 May 2013.</ref. Láwọn àsìkò kan tí Oòrùn kò bá mú dà bí nkan láwọn agbègbè ọ̀ọ̀kan, èyí lè mú kí irì ó dì pọ̀ kó di yìnyín, ní èyí tí wọ́n ń pè ìkórajọ pọ̀ yí ní (frost) Nígb tí ó jẹ́ wípé irì níṣe pẹ̀lú bí ojú-ọjọ́ bá ṣe rí tàbí gbóná sí, ó sábà ma ń sẹ̀ sí ara àwọn nkan bíi ewé, koríko, ojú irin ọkọ̀ ojú-irin, orí tàbí ara ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ àti bẹ̀ẹ́ nẹ̀ẹ́ lọ.
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.