Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà (Africa Cup of Nations tabi African Cup of Nations tabi African Nations Cup, lonibise bi CAN (Faranse fun Coupe d'Afrique des Nations), ni idije boolu-elese akariaye ni Afrika. O wa labe akoso Ijoparapo Boolu-elese Afrika (CAF), o si koko waye ni 1957. Lati 1968, o ti n waye leyin odoodun meji.