![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/3/38/Sign_for_African_Nations_Cup.jpg/640px-Sign_for_African_Nations_Cup.jpg&w=640&q=50)
Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ife Ẹ̀yẹ àwọn Orílẹ̀-èdè Áfríkà (Africa Cup of Nations tabi African Cup of Nations tabi African Nations Cup, lonibise bi CAN (Faranse fun Coupe d'Afrique des Nations), ni idije boolu-elese akariaye ni Afrika. O wa labe akoso Ijoparapo Boolu-elese Afrika (CAF), o si koko waye ni 1957. Lati 1968, o ti n waye leyin odoodun meji.
Quick Facts Ìdásílẹ̀, Agbègbè ...
Ìdásílẹ̀ | 1957 |
---|---|
Agbègbè | Áfríkà (CAF) |
Iye ẹgbẹ́ agbábọ́ọ̀lù | 16 |
Aborí Lọ́wọ́ | ![]() |
Lọ́wọ́ | ![]() |
Close
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/3/38/Sign_for_African_Nations_Cup.jpg/640px-Sign_for_African_Nations_Cup.jpg)