Àwọn Ajọọmọnìyàn
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ajọ́bọ (Ape) je eyikeyi ninu ébi gbangba Àwọn Aríbíèyàn (Hominoidea) ti awon akodieyan, ninu won na ni awon eniyan wa.
Quick Facts Àwọn Ajọ̀bọ Apes Temporal range: Late Oligocene - Recent, Ìṣètò onísáyẹ́nsì ...
Àwọn Ajọ̀bọ Apes[1] Temporal range: Late Oligocene - Recent | |
---|---|
Lar Gibbon (Hylobates lar) | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì | |
Ìjọba: | |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | |
Ìtò: | Àwọn Akọ́dièyàn {Primates} |
Suborder: | Haplorrhini |
Infraorder: | Simiiformes |
Parvorder: | Catarrhini |
Superfamily: | Àwọn Aríbíèyàn (Hominoidea) Gray, 1825 |
Families | |
Hylobatidae |
Close
Labe sistemu iyasoto lowo awon ebi meji awon aribieyan lowa:
- ebi Hylobatidae to ni apa 4 ati iru eya 14 awon gibo, ninu won ni Gibo Lar ati Siamang wa, lapapo won je awon ajobo kekere.
- ebi awon Ajoeyan (Hominidae) ninu won ni awon osa, awon gorilla, awon eniyan ati awon orangutan[1][2] lapapo a mo won bi awon ajobo ninla.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |