Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì ni ikan ninu awon egbe oloselu ninla meji igba oni ni Amerika, po mo Egbe Republikani. Idurole alanidekun awujo ati arewaju egbe na je gbigba bi arin-owo-osi ninu ibu oselu Amerika.[1][2][3] Egbe yi ni rekodu isise ni Amerika togunjulo, be sini o je ikan larin awon egbe oloselu to gbojulo lagbaye.[4] Egbe yii ni omo-egbe milionu 72 ti o ti foruko sile ni odun 2004.[5] Ogbeni Barack Obama ni Demokrati 15k ti yio bo sipo Aare orile-ede Amerika.
Ẹgbẹ́ Dẹmọkrátíkì Democratic Party | |
---|---|
Chairperson | Tom Perez |
Senate Leader | Chuck Schumer (Minority Leader) (NY) |
House Leader | Nancy Pelosi (CA) |
Chair of Governors Association | Jay Inslee (WA) |
Ìdásílẹ̀ | 1828 (modern) 1792 (historical) |
Ibùjúkòó | 430 South Capital Street SE, Washington, D.C., 20003 |
Ẹ̀ka akẹ́kọ̀ọ́ | College Democrats of America |
Ẹ̀ka ọ̀dọ́ | Young Democrats of America |
Ọ̀rọ̀àbá | Modern: American liberalism Third Way Progressivism Internal factions: • Progressive Democrats • Libertarian Democrats • Moderate Democrats • Conservative Democrats Historical: Jacksonian democracy Classical liberalism Bimetallism States' rights Paleoconservatism |
Ìbáṣepọ̀ akáríayé | Alliance of Democrats |
Official colors | Blue |
Position in national political spectrum | Center-left |
Seats in the Senate | 47 / 100 |
Seats in the House | 194 / 435 |
Governorships | 16 / 50 |
State Upper Houses | 921 / 1,921 |
State Lower Houses | 2,368 / 5,410 |
Ibiìtakùn | |
http://www.democrats.org/ |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
Wikiwand in your browser!
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.