From Wikipedia, the free encyclopedia
Dag Hjalmar Agne Carl Hammarskjöld ( Dag Hammarskjöld (ìrànwọ́·ìkéde)) (29 July 1905 – 18 September 1961) je diplomati, onimo oro-okowo ati oludako ara Swidin. O je Akowe Agba keji Aparapo awon Orile-ede lati April 1953 titi di ojo to se alaisi ninu ijamba baalu ni September 1961. Ohun nikan ni o gba Ebun Alafia Nobel leyin to se alaisi.[1] Bakanna Hammarskjöld nikan na tun ni Akowe Agba U.N. to se alaisi lenu ise.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.