Dọ́là
From Wikipedia, the free encyclopedia
Dọ́là ni oruko owonina fun ibise ni opolopo awon orile-ede ile-ijoba bi Australia, New Zealand, Canada, awon agbegbe Eastern Caribbean territories, Hong Kong, Taiwan, Singapore, Brunei, East Timor, Ecuador, El Salvador, Panama, Belize ati ni Orile-ede Amerika.