![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/f/fa/Flag_of_Botswana.svg/langyo-640px-Flag_of_Botswana.svg.png&w=640&q=50)
Bòtswánà
From Wikipedia, the free encyclopedia
Bòtswánà, lóníbiṣẹ́ bíi Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà (Tswana: [Lefatshe la Botswana] error: {{lang}}: text has italic markup (help)), jẹ́ orílẹ̀-èdè àdèmọ́àrinlẹ̀ tó bùdó sí Apágúsù Áfríkà. Àwọn ọmọ orílẹ̀-èdè únpe ara wọn bíi "Batswana" (ẹyọìkan: Motswana), sugbon awon elede miran unpe won bi "ara Botswana". Teletele o je ibi-abo Britani to unje Beshuanalandi, Botswana gba oruko tuntun leyin ominira ni ojo 30 Osu Kesan 1966. Latigba na lo lo ti unse idiboyan oselu to gbomitoro.
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Bòtswánà Republic of Botswana Lefatshe la Botswana | |
---|---|
Motto: Pula (Òjò) | |
![]() Ibùdó ilẹ̀ Bòtswánà (dark blue) – ní Africa (light blue & dark grey) | |
Olùìlú | Gaborone |
Ìlú tótóbijùlọ | olúìlú |
Àwọn èdè ìṣẹ́ọba | Gẹ̀ẹ́sì Setswana |
Àwọn ẹ̀yà ènìyàn | Tswana 79% Kalanga 11% Basarwa 3% Kgalagadi 3% White African 3% òmíràn 1% |
Orúkọ aráàlú | Batswana/Motswana |
Ìjọba | Orílẹ̀-èdè olómìnira oníléaṣòfin |
• Ààrẹ | Mokgweetsi Masisi |
• Igbákejì Ààrẹ | Slumber Tsogwane |
Aṣòfin | Ilé Ìgbìmọ̀ Aṣòfin |
Ìlómìnira | |
• látòdọ̀ Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan | 30 September 1966 |
Ìtóbi | |
• Total | 581,730 km2 (224,610 sq mi) (47k) |
• Omi (%) | 2.6 |
Alábùgbé | |
• 2010 estimate | 2,029,307[1] (144k) |
• 2001 census | 1,680,863 |
• Ìdìmọ́ra | 3.4/km2 (8.8/sq mi) (229k) |
GDP (PPP) | 2011 estimate |
• Total | $29.707 billion[2] |
• Per capita | $16,029[2] |
GDP (nominal) | 2011 estimate |
• Total | $17.570 billion[2] |
• Per capita | $9,480[2] |
Gini (1993) | 63[3] Error: Invalid Gini value |
HDI (2010) | ▲ 0.633[4] Error: Invalid HDI value · 98th |
Owóníná | Pula (BWP) |
Ibi àkókò | Central Africa Time (UTC+02) |
• Ìgbà oru (DST) | kòsí |
Ojúọ̀nà ọkọ́ | òsì |
Àmì tẹlifóònù | +267 |
ISO 3166 code | BW |
Internet TLD | .bw |
Botswana je petele, be sini 70% je bibomole pelu Aginju Kalahari. O ni bode mo orile-ede Guusu Afrika ni gusu ati gusuilaorun, Namibia ni iwoorun ati ariwa, ati Zimbabwe ni ariwailaorun. Bode re mo Zambia ni ariwa nitosi Kazungula, Zambia ko fi be nitumo sugbon ko gun ju bi ogorun mita lo. [5]
Botswana ko ni ju eniyan to to egbeegberun meji lo nitorie o je ikan ninu awon orile-ede alabugbe kekere julo ni agbaye. Nigba ti Botswana gba ilominira latowowo Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan ni 1966, o je ikan ninu awon orile-ede to talaka julo ni Afrika pelu GDP ti enikookan bi US$70. Latigbana Botswana ti yira re pada lati di ikan ninu awon ti okowo re undagba julo lagbaye de eyi to ni GDP (agbara iraja) ti enikookan to to bi $14,000.[1] Bakana asa oselu asoju gbale daada nibe.