From Wikipedia, the free encyclopedia
Beyoncé Giselle Knowles ( /biˈjɒnseɪ/ bee-YON-say; bíi Ọjọ́ kẹrin Oṣù kẹsán Odún 1981), tí wọ́n mọ̀ sí Beyoncé jẹ́ alágbe tí ó ń kọ R&B àti ẹlẹ́ṣọ́ aṣọ ọmọ orílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà. Wọ́n bíi ní Houston ní Texas, níbi tó ti lọ sí ilé ẹ̀kọ́ iṣẹ́ ọnà síṣe. Knowles kọ́kọ́ gbajúmọ̀ ní òpin èwádún 1990 gẹ́gẹ́ bí asíwájú akọrin ẹgbẹ́ olórin R&B Destiny's Child, ìkan nínú àwọn ẹgbẹ́ olórin lóbìnrin tí ó tàjùlọ lágbáyé.
Beyoncé Knowles | |
---|---|
Knowles in 2013 | |
Background information | |
Orúkọ àbísọ | Beyoncé Giselle Knowles |
Ọjọ́ìbí | 4 Oṣù Kẹ̀sán 1981[1] |
Ìbẹ̀rẹ̀ | Houston, Texas, United States |
Irú orin | R&B, pop, soul, hip hop |
Occupation(s) | Singer, songwriter, record producer, actress, dancer, entertainer, choreographer, model, video director |
Years active | 1997–present |
Labels | Columbia |
Associated acts | Destiny's Child, Jay-Z, Solange Knowles |
Website | beyonceonline.com
Beyoncé's autograph |
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.