Baeyer–Emmerling indole synthesis
From Wikipedia, the free encyclopedia
Baeyer–Emmerling indole synthesis jẹ́ ọ̀nà fún ìṣètò indole lati (ìrọ́pò) ortho-nitrocinnamic acid àti iron gbẹrẹfu nínú àpòpọ̀ base tó le.[1][2] Ẹni tí ó ṣe àwàrí ìdàpapọ̀ ṣiṣẹ́ yìí ni Adolf von Baeyer àti Adolph Emmerling ní ọdún 1869.[3] [4]
![Baeyer-Emmerling indole synthesis](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/6/69/Baeyer-Emmerling-indoolsynthese.png/640px-Baeyer-Emmerling-indoolsynthese.png)