Olori tí atún mò sí Aya Ọba tàbí iyawo oba jé iyawo sí oba tówà ní orí oyè. Ní àwon ìlú tàbí agbegbe tí asa wón gbà ki oba fé ju iyawo kan lo, a le pe gbogbo ìyàwó oba ní ayaba. Bí o tile jé wípé ayaba jé eni iyi ní awujo, ko ní agbara kankan lowo ararè ní òpòlopò àsà, bi ní orílè-èdè United Kingdom(Ilẹ̀ọba Aṣọ̀kan) ati ní Ile Yorùbá. [1]

Àwon Ìtókasí

Wikiwand in your browser!

Seamless Wikipedia browsing. On steroids.

Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.

Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.