![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/5/57/1.Mai_2013_%25288697603319%2529.jpg/640px-1.Mai_2013_%25288697603319%2529.jpg&w=640&q=50)
Ayájọ́ ọjọ́ òṣìṣẹ́ lágbàáyé
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ayájọ́ ọjọ́ àwọn òṣìṣẹ́ tí wọ́n tún ma ń pè ní May Day,[1][2] ni ó jẹ́ ọjọ́ ìsinmi àti ajọyọ̀ àwọn òṣìṣẹ́ káàkiri àgbáyé tí ó ma ń wáyé ní ọjọ́ kínní osù Karùn un ní gbogbo ọdọdún .[3][4][5]
Quick Facts International Workers' Day, Official name ...
Close