Ọkọ ẹrú Barbary
From Wikipedia, the free encyclopedia
Oko ẹrú Barbary jẹ́ àwọn ọjà ẹrú tí ó wà ní àwọn Ìpínlẹ̀ Barbary. Àwọn jàndùkú odò tí ó jẹ́ ọmọ Barbary ya wọ àwọn ọkọ̀ ojú omi, ìlú ẹgbẹ́ odò láti Italy dé Netherland, Ireland àti gúúsù apá ìwọ̀ oòrùn Britain, títí dé àríwá Iceland àti Ìlà-Oòrùn Mediterra.
Apá ìlà-oòrùn Mediterranean Ottoman ni ìṣẹ̀lẹ̀ yí wọ́sí jùlọ.[1] Títí di àwọn ọdún 1700s, ìwà jàndùkú jẹ́ ǹkan tí ó sì ń da Aegean láàmú.[2]