Ìjalèlókun
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìjalèlókun jẹ́ ìwa olèjíjà tàbí ìwà ọ̀daràn ní okun. Àwọn tí ó ń lọ́wọ́sí ìwà Ìjalèlókun ni wọ́n ń pè ní àwọn ajalèlókun. Àkosílẹ̀ àpẹẹrẹ ìjalèlókun tí ó pẹ́jù ṣẹlẹ̀ ní bíi Orundún mẹ́rìnlá sẹ́yìn, nígbà tí àwọn ẹgbẹ́ ajalè lórí òkun dojú kọ ọkọ̀ ojú omi ti Aegean àti Mediterranean tí kò digun. Àwọn ònà tóóró tí ó ń jẹ́ kí wọn mọ ònà ibi tí ọkọ̀ ojú omi gbà ń fa ààyè fún ìjalèlókun,[1] tí ó tún ń fa ààfàní fún idigun ja ọkọ̀ ojú omi àti oníṣowò ojú omi.