![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/9/98/Patriotism_by_Francisco_P%25C3%25A9rez_del_Valle_%2528Madrid%2529_01.jpg/640px-Patriotism_by_Francisco_P%25C3%25A9rez_del_Valle_%2528Madrid%2529_01.jpg&w=640&q=50)
Ìfẹ́ Orílẹ́-èdè Ẹni
From Wikipedia, the free encyclopedia
Ìfẹ́ Orílẹ́-èdè Ẹni jẹ́ aáyan ìfọkànsìn láti fìfẹ́hàn fún orílẹ̀-èdè ẹni ní ìfọwọ́sọwọ́pọ̀ pẹ̀lú àwọn ará ìlú tí ìṣẹ̀dá wọn jọra. Èyí lè jẹ́ àpapọ̀ orísìírísìí àdámọ́ tó jẹ mọ́ ìlú ẹni; lára wọn ni ẹ̀yà, àṣà, ètò-òṣèlú tàbí ìtàn ìṣẹ̀dálẹ̀. Ó jẹ́ àkójọpò ìmọ̀ tó sunmo ìgbórílẹ̀-èdè ẹni ga (nationalism).[1][2][3]
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/9/98/Patriotism_by_Francisco_P%C3%A9rez_del_Valle_%28Madrid%29_01.jpg/640px-Patriotism_by_Francisco_P%C3%A9rez_del_Valle_%28Madrid%29_01.jpg)