Átẹ́gùn Ooru
From Wikipedia, the free encyclopedia
Átẹ̀gun Óóru jẹ óóru to làgbàrà nigba asiko óju ọjọ to gbónà[1][2]. ọriniinitutu giga maa nwa pẹ̀lu Átẹ̀gun Óóru. Èyi maa nṣẹlẹ ni órilẹ èdè tí o ni ójù ọjọ tó fara pẹ ókun[3].
Ìwọn Átẹgun óórù jẹ ìbàtàn fun ọju ọjọ àgbègbè ati deede otutu fun igba. Óóru to wa lati àgbègbè awọ̀n eniyan to wa ni ójù ọjọ gbigbóna jẹ Átẹgun óórù fun awọn ti oun gbè ni agbègbè to tutu. Èyi maa ṣẹlẹ ti gbìgbona otutu ba yatọ̀ si apẹrẹ ójù ọjọ fun àgbègbè naa[4]. Átẹgun óórù wọpọ to dẹ tun làgbàrà lori ilẹ kàkirì àgbègbè lati ọdun 1950s latari Àyipadà ójù ọjọ[5].
Átẹgun óórù to lagbara maa njẹki ohun ọgbin bajẹ, Ooru yi jẹ a lèkun fun iṣẹlẹ iná ninu igbó ni awujọ ọgbẹ̀lẹẹ[6][7]. Eyi maa jasi àyipada inà ijọba nitori imulètutu ti awọn èniyan ló.
Átẹgun óórù jẹ ójù ọjọ to làgbàrà eyi lo ma fa ailèrà fún awọn èniyan nitóri óóru ati óórun maa nbóri awọn ẹ̀yàeto itutu ara eniyan[8]. Ó ṣèṣè latiri Átẹgun óórù pẹ̀lù awọn ìrìnṣẹ Àfojúsùn ojú ọjọ.