![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/bf/Map_of_the_African_Union_with_Suspended_States.svg/langyo-640px-Map_of_the_African_Union_with_Suspended_States.svg.png&w=640&q=50)
Àwọn orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ African Union
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwọn Orílẹ̀ ède márùnléládọ́ta ni wọ́n jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ African Union (AU).[1] AU jẹ́ ègbé tó rọ́pòOrganisation of African Unity (OAU), àyè sì ṣí ní AU láti gba àwọn tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ OAU.
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/b/bf/Map_of_the_African_Union_with_Suspended_States.svg/640px-Map_of_the_African_Union_with_Suspended_States.svg.png)
Nígbà tí ó ṣe ma di ọdún 2017, àjọ AU ti dé gbogbo orílẹ̀ èdè ní Áfríkà, yàtò sí àwọn ilẹ̀ Spanish North Africa ti Ceuta, Melilla, àti Vélez de la Gomera.Iye olùgbé àwọn orílẹ̀ èdè AU jẹ́ 1,068,444,000 (ní ọdún 2013)