![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/17/Regions_of_the_African_Union.png/640px-Regions_of_the_African_Union.png&w=640&q=50)
Àwọn agbègbè African Union
From Wikipedia, the free encyclopedia
African Union (AU) pín àwọn orílẹ̀ èdè tó jẹ́ ara rẹ̀ sí márùn-ún.[1] Wọ́n ti ka àwọn ọmọ Àwùjọ Áfríkà, èyí tó jẹ́ àwọn ọmọ Áfríkà ṣùgbọ́n tí wọn ń gbé ní orílẹ̀ míràn bi Amẹ́ríkà, Australia, Asia, àti Europe, gẹ́gẹ́ bi àgbègbè Africa Union kẹfà.[2]
Ká mọ́ ṣe àṣìṣe rẹ̀ mọ́ Àtòjọ àwọn agbègbè ní Áfríkà.
![Thumb image](http://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/1/17/Regions_of_the_African_Union.png/320px-Regions_of_the_African_Union.png)
Àríwá
Gúúsù
Ìlà oòrùn
Ìwọ oòrùn A àti B
Àárín
Note that the African Union includes the African diaspora as a region and that Ceuta and Melilla in North Africa are part of Spain.