Àtòjọ àwọn oúnjẹ Ilẹ̀ Adúláwọ̀
From Wikipedia, the free encyclopedia
Àwọn wọ̀nyí ni àtòjọ àwọn oúnjẹ Ilẹ̀ Adúláwọ̀, Áfíríkà. Ilẹ̀ Áfíríkà jẹ́ ilẹ̀ kejì tó tóbi jù ní àgbáyé, pẹ̀lú oríṣiríṣi àṣà, ẹyà àti ènìyàn pẹ̀lú oríṣiríṣi oúnjẹ. Àwọn ẹ̀yà kọ̀ọ̀kan ló sìn ní oúnjẹ kọ̀ọ̀kan wọn, àwọn nǹkan tí wọ́n fi ń sè é àti bí wọ́n ṣe ń sè é.