Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn Lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
From Wikipedia, the free encyclopedia
From Wikipedia, the free encyclopedia
Èyí ni Àtòjọ Àwọn Ìwé-ìròyìn tí wọ́n ń tẹ̀ jáde tí wọ́n sìn ń tà lórílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà
Títí di 2014[update], iye ìwé ìròyìn ojoojúmọ́ tí wọ́n wà lórílẹ̀ èdè Amẹ́ríkà jẹ́ 1,331.[1]
Àwọn wọ̀nyí ni mẹ́wàá nínú àwọn ìwé-ìròyìn Amẹ́ríkà tó gbajúmọ̀ jùlọ ní títàn káàkiri lóòjọ́ lọ́sẹ̀, tí kìí ṣe ọ̀fẹ́. [2]
Rank | Orúkọ Ìwé-ìròyìn | Àgbègbè tí wọ́n wà | Olú ìlú tàbí ìpínlẹ̀ tí wọ́n wà | Àpapọ̀ iye tí wọ́n ń gbé jáde | Olùdásílẹ̀ | Orúkọ Ìṣẹ̀dá lẹ̀ rẹ̀ |
---|---|---|---|---|---|---|
1 | USA Today | McLean, Virginia | Virginia | 1,621,091 | Gannett Company | |
2 | The Wall Street Journal | New York City | New York | 1,011,200 | News Corp | |
3 | The New York Times | New York City | New York | 483,701 | The New York Times Company | |
4 | New York Post | New York | New York | 426,129 | News Corp | |
5 | Los Angeles Times | Los Angeles | California | 417,936 | Nant Capital | |
6 | The Washington Post | Washington D.C. | District of Columbia | 254,379 | Nash Holdings | |
7 | Star Tribune | Minneapolis | Minnesota | 251,822 | Star Tribune Media Company | |
8 | Newsday | Melville | New York | 251,473 | Newsday Media Group | |
9 | Chicago Tribune | Chicago | Illinois | 238,103 | Tribune Publishing Company | |
10 | Boston Globe | Boston | Massachusetts | 230,756 | Boston Globe Media Partners |
Àtòjọ Àwọn àtòjọ Ìwé-ìròyìn:
Seamless Wikipedia browsing. On steroids.
Every time you click a link to Wikipedia, Wiktionary or Wikiquote in your browser's search results, it will show the modern Wikiwand interface.
Wikiwand extension is a five stars, simple, with minimum permission required to keep your browsing private, safe and transparent.