![cover image](https://wikiwandv2-19431.kxcdn.com/_next/image?url=https://upload.wikimedia.org/wikipedia/commons/thumb/c/c5/Leopard_africa.jpg/640px-Leopard_africa.jpg&w=640&q=50)
Àmọ̀tẹ́kùn
Ẹranko / From Wikipedia, the free encyclopedia
Fún ẹranko tí Yorùbá ńpè ní Àmọ̀tẹ́kùn, ẹ wo ojú ewé
Quick Facts ẸkùnLeopard Temporal range: Early Pleistocene to recent, Ipò ìdasí ...
Ẹkùn Leopard Temporal range: Early Pleistocene to recent[1] | |
---|---|
![]() | |
Fọ́tò Ẹkùn Áfríkà (P. p. pardus) | |
Ipò ìdasí | |
Ìṣètò onísáyẹ́nsì [ edit ] | |
Ìjọba: | Animalia (Àwọn ẹranko) |
Ará: | Chordata |
Ẹgbẹ́: | Mammalia (Àwọn afọmúbọ́mọ) |
Ìtò: | Ajẹran |
Suborder: | Ajọ-ológìnní |
Ìdílé: | Ẹ̀dá-ológìnní |
Subfamily: | Pantherinae |
Ìbátan: | Panthera |
Irú: | P. pardus[3] |
Ìfúnlórúkọ méjì | |
Panthera pardus[3] (Linnaeus, 1758) | |
Subspecies | |
See text | |
![]() | |
Present and historical distribution of the leopard[2] |
Close
Ẹkùn (Panthera pardus) ni ìkan nínú àwọn irú ẹranko márùn tó wà láyé nínú ìbátan Panthera, ìkan nínú àwọn Ẹ̀dá-olóngbò.[4] Ó pọ̀ káà kiri ní agbègbè Ìsàlẹ̀-Sàhárà Áfríkà, ní àwọn agbègbè kan ní apá Ilàòrùn àti Arin Asia, ní ìsàlẹ̀orílẹ̀ India dé apá Gúúsù-ìlàòrùn àti Ìlàòrùn Asia.