Tessa Thompson
From Wikipedia, the free encyclopedia
Tessa Lynne Thompson (tí a bí ní ọjọ́ kẹta oṣù kẹsàn-án ọdún 1983) jẹ́ òṣèrébìnrin ọmọ orílẹ̀ èdè Amerika. Ó bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí òṣèré pẹ̀lú ilé isé Los Angeles Women's Shakespeare nígbà tí ó ń kàwé ní ilé ìwé Santa Monica College. Ó wà nínú eré The Tempest àti Romeo and Juliet, ipa rẹ̀ nínú eré Romeo and Julie sì mú kí wọ́n yàn fún àmì-ẹ̀yẹ NAACP Theatre Award. Ó gbajúmọ̀ nígbà tí ó ṣeré nínú fíìmù tí Tina Mabry ṣàgbéjáde; Mississippi Damned (2009) àti fíìmù Tyler Perry tí àpèlé rẹ̀ jẹ́ For Colored Girls (2010).
Quick Facts Ọjọ́ìbí, Iléẹ̀kọ́ gíga ...
Tessa Thompson | |
---|---|
Thompson ní San Diego Comic-Con ní ọdún 2019 | |
Ọjọ́ìbí | Tessa Lynne Thompson 3 Oṣù Kẹ̀wá 1983 (1983-10-03) (ọmọ ọdún 40) Los Angeles, California, U.S. |
Iléẹ̀kọ́ gíga | Santa Monica College |
Iṣẹ́ | Actress |
Ìgbà iṣẹ́ | 2002–present |
Àwọn olùbátan | Zsela (half-sister) |
Close